
Ọ̀rọ̀ inú fídíò Tiktok tó sọ pé Ibrahim Traore sọ pé kí àwọn ará Burkina Faso má san owó orí kìí se òótọ́
Ẹni kan tí wọ́n ń pè ní @Panafrica069 lórí Tiktok, ohun ìgbàlódé ibaraẹnise tí àwọn ènìyàn ti máa ń fi àwòrán/fídíò síta, ti sọ pé Ibrahim Traore, olórí ijoba Ológun ni Orílẹ̀ èdè Burkina Faso tí sọ pé kí àwọn tó ń ṣòwò tàbí se ọ̀rọ̀ ajé má san owó orí …